MENU

Ẹ̀SAN

Ẹ̀SAN

Afipá lówó wọn kì í ká dún

Afi wàrà wàrà là bí ológbu wọn kì í d’ọ̀la

Bó pẹ́ títí n óò lówó lọ́wọ́ ń bẹ l’ ábà tí ń jẹ ẹ̀sun iṣu

Ọjọ́ ẹ̀san ò lọ títí kò j’ọ́rọ̀ ó dun ni

Iyán ogún ọdún, a máa jó ní lọ́wọ́

Ẹni ṣe rere, kó máa ṣe lọ, ẹni ń ṣè’kà, kó máa ṣé bọ̀

Ẹ̀san á ké bí àrá.

All Rights reserved

©Jógunómí

+2348069672484

rasheedtemitope5@gmail.com

Share this post

Share on facebook
Facebook
Share on twitter
Twitter
Share on linkedin
LinkedIn
Share on whatsapp
WhatsApp
Share on email
Email

Leave a Reply

Your email address will not be published.